SARS-CoV-2
Severe acute respiratory syndrome coronavirus 2 | |
---|---|
Transmission electron micrograph of SARS-CoV-2 virions with visible coronae | |
Illustration of a SARS-CoV-2 virion[1] | |
Ìṣètò ẹ̀ràn [ e ] | |
(unranked): | Èràn |
Realm: | Riboviria |
Ará: | Incertae sedis |
Ìtò: | Nidovirales |
Ìdílé: | Coronaviridae |
Ìbátan: | Betacoronavirus |
Subgenus: | Severe acute respiratory syndrome-related coronavirus |
Irú: | |
Irú-ìdá: | Severe acute respiratory syndrome coronavirus 2
|
Synonyms | |
|
Kòkòrò èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró, èrànkòrónà irú 2 tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ sáyẹ́nsì rẹ̀ SARS-CoV-2 (Severe acute respiratory syndrome coronavirus 2)[2] tàbí tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ bíi èrànkòrónà Wuhan[3] tàbí èrànkòrónà tuntun 2019 (2019 novel coronavirus, 2019-nCoV)[4][5] jẹ́ èrànkòrónà kan pẹ̀lú èròjà àbímọ́ RNA adáraṣe pẹ̀lú ẹnu-igun apọ̀si
Kòkòrò èràn yìí ni ó fa àrùn COVID-19, tó jẹ̀ àrùn alákòóràn láàrin àwọn ènìyàn. Kò sí ògùn ìbupánaunba fún kòkòrò èràn yìí. Nítoríẹ̀ Àjọ Ilèra Àgbáyé ti pe àjákálẹ̀ àrùn COVID-19 tó ún lọ lọ́wọ́ ní Pàjáwìrì Ilera Ìgboro tó kan gbogbo Ayé[6][7][8].
Ìtò sí àyè rẹ̀ fi hàn pè, SARS-CoV-2 jẹ́ irú kòkòrò àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró tó jẹ mọ́ erànkòrónà (SARSr-CoV). Ìgbágbọ́ ni pé ọ̀dọ̀ àwọn ẹranko ló ti wá nítorí pé ó ní ìjọra mọ́ àwọn kòkòrò èrànkòrónà àdán[9][10][11][12].
Àwọn ìwádìí ẹ̀kọ́ ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn díye pé ẹni tó bá ní kòkòrò èràn yìí le kóoran àwọn elòmíràn tuntun tótó 1.4 sí 3.9 tí ẹnìkankan láwùjọ kó bá ní àjẹsára àti tí kó sì sí ètò ìjánu àrùn kankan. Kòkòrò èràn yìí ún ràn ká nípa fífara kan ara àti nípa wíwúkọ́ tàbí sísín.[13][14] Ó ún wọ nú ìhámọ́ ara ènìyàn nípa síso mọ́ angiotensin converting enzyme 2 (ACE2).[9][15][16]
Ọrúkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbàtí ìjálẹ̀ àrùn náà kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní ilú Wuhan ní Ṣáínà, orúkọ tí wọ́n sábà pe kòkòrò èràn náà nígbà náà ni "èrànkòrònà (coronavirus)", "èrànkòrònà Wuhan (Wuhan coronavirus)",[17][18][19] tàbí "èràn Wuhan (Wuhan virus)".[20][21] Ní January ọdún 2020, Àjọ Ìlera Àgbáyé dáàbá orúkọ "èrànkòrónà tuntun ọdún 2019 (2019 novel coronavirus)" (2019-nCov)[22][23] fún kòkòrò èràn náà. Èyí ní ìbámu mọ́ ìlànà AIA (WHO) ọdún 2015[24] tó lòdì sí lílo orúkọ ibùgbé (f.a. Wuhan), orúkọ irú ẹranko, tàbí orúkọ ẹ̀yà ènìyàn fún orúkọ àrùn tàbí kòkòrò èràn.[25][26] Ní 11 February 2020, ìgbìmọ̀ International Committee on Taxonomy of Viruses (Ìgbìmọ̀ Àgbáyé lórí Ìpínsíàyè àwọn Kòkòrò Èràn) gba orúkọ yìí "àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró, èrànkòrónà irú 2" (severe acute respiratory syndrome coronavirus 2; SARS-CoV-2) gẹ́gẹ́ bíi orúkọ àlòsiṣẹ́.[27] Láti mọ́ baà ṣe àsìṣe rẹ̀ m àrùn SARS, Àjọ Ìlera Àgbáyé nígbà míràn le pe SARS-CoV-2 bi "the COVID-19 virus" (èràn COVID-19) nínú àwọn ìkéde wọn.[28][29] Àwọn míràn tún pe SARS-CoV-2 àti àrùn rẹ̀ bíi "àrùn kòrónà" tàbí "kòkòrò kòrónà".
Ìmọ̀ kòkòrò èràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The Spiky Blob Seen Around the World". The New York Times. 1 April 2020. https://www.nytimes.com/2020/04/01/health/coronavirus-illustration-cdc.html.
- ↑ "Naming the coronavirus disease (COVID-19) and the virus that causes it". who.int. Retrieved 20 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "COVID-19 CORONAVIRUS OUTBREAK". worldometers.info. Retrieved 20 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Surveillance case definitions for human infection with novel coronavirus (nCoV)". www.who.int (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-21.
- ↑ "Novel coronavirus (2019-nCoV), Wuhan, China". cdc.gov. 10 January 2020. Retrieved 16 January 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "WHO Director-General's opening remarks at the media briefing on COVID-19 - 11 March 2020". World Health Organization (WHO) (Press release). 11 March 2020. Archived from the original on 11 March 2020. Retrieved 12 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "W.H.O. Declares Global Emergency as Wuhan Coronavirus Spreads". 30 January 2020. https://www.nytimes.com/2020/01/30/health/coronavirus-world-health-organization.html.
- ↑ "A familial cluster of pneumonia associated with the 2019 novel coronavirus indicating person-to-person transmission: a study of a family cluster". The Lancet 395 (10223): 514–523. February 2020. doi:10.1016/S0140-6736(20)30154-9. PMC 7159286. PMID 31986261. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7159286.
- ↑ 9.0 9.1 "A pneumonia outbreak associated with a new coronavirus of probable bat origin". Nature 579 (7798): 270–273. February 2020. doi:10.1038/s41586-020-2012-7. PMC 7095418. PMID 32015507. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7095418.
- ↑ "Another Decade, Another Coronavirus". The New England Journal of Medicine 382 (8): 760–762. February 2020. doi:10.1056/NEJMe2001126. PMC 7121143. PMID 31978944. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7121143.
- ↑ "The 2019-new coronavirus epidemic: Evidence for virus evolution". Journal of Medical Virology 92 (4): 455–459. April 2020. doi:10.1002/jmv.25688. PMC 7166400. PMID 31994738. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7166400.
- ↑ "Correspondence: The proximal origin of SARS-CoV-2". Nature Medicine 26 (4): 450–452. 17 March 2020. doi:10.1038/s41591-020-0820-9. PMC 7095063. PMID 32284615. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7095063.
- ↑ "Q&A on coronaviruses (COVID-19)". World Health Organization (WHO). 11 February 2020. Archived from the original on 20 January 2020. Retrieved 24 February 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "How COVID-19 Spreads". U.S. Centers for Disease Control and Prevention (CDC). 27 January 2020. Archived from the original on 28 January 2020. Retrieved 29 January 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Functional assessment of cell entry and receptor usage for SARS-CoV-2 and other lineage B betacoronaviruses". Nature Microbiology 5 (4): 562–569. February 2020. doi:10.1038/s41564-020-0688-y. PMC 7095430. PMID 32094589. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7095430.
- ↑ "SARS-CoV-2 Cell Entry Depends on ACE2 and TMPRSS2 and Is Blocked by a Clinically Proven Protease Inhibitor". Cell 181 (2): 271–280.e8. 16 April 2020. doi:10.1016/j.cell.2020.02.052. PMC 7102627. PMID 32142651. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7102627.
- ↑ Huang P (22 January 2020). "How Does Wuhan Coronavirus Compare with MERS, SARS and the Common Cold?". NPR. Archived from the original on 2 February 2020. Retrieved 3 February 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "What you need to know about the Wuhan coronavirus". Nature. 24 January 2020. doi:10.1038/d41586-020-00209-y.
- ↑ "GOP lawmakers continue to use 'Wuhan virus' or 'Chinese coronavirus'". NBC News. 12 March 2020. https://www.nbcnews.com/news/asian-america/cdc-chief-spurns-term-chinese-coronavirus-used-gop-lawmakers-n1156656.
- ↑ "US push to include 'Wuhan virus' language in G7 joint statement fractures alliance". CNN. 26 March 2020. https://www.cnn.com/2020/03/25/politics/g7-coronavirus-statement/index.html.
- ↑ "Wuhan virus sees Olympic football qualifiers moved". Xinhua. 22 January 2020. Archived from the original on 22 January 2020. https://web.archive.org/web/20200122202501/http://www.xinhuanet.com/english/2020-01/22/c_138727094.htm.
- ↑ Novel Coronavirus (2019-nCoV): situation report, 10. World Health Organization. 30 January 2020.
- ↑ "Healthcare Professionals: Frequently Asked Questions and Answers". United States Centers for Disease Control and Prevention (CDC). 11 February 2020. Archived from the original on 14 February 2020. Retrieved 15 February 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Health Organization Best Practices for the Naming of New Human Infectious Diseases" (PDF). WHO. May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Novel coronavirus named 'Covid-19': WHO". TODAYonline. https://www.todayonline.com/world/wuhan-novel-coronavirus-named-covid-19-who.
- ↑ "The coronavirus spreads racism against—and among—ethnic Chinese". The Economist. 17 February 2020. https://www.economist.com/china/2020/02/17/the-coronavirus-spreads-racism-against-and-among-ethnic-chinese.
- ↑ Novel Coronavirus (2019-nCoV): situation report, 22. World Health Organization. 11 February 2020.
- ↑ "Why won't the WHO call the coronavirus by its name, SARS-CoV-2?". Quartz. 18 March 2020. https://qz.com/1820422/coronavirus-why-wont-who-use-the-name-sars-cov-2/.
- ↑ "Naming the coronavirus disease (COVID-2019) and the virus that causes it". World Health Organization. Archived from the original on 28 February 2020. Retrieved 24 February 2020.
From a risk communications perspective, using the name SARS can have unintended consequences in terms of creating unnecessary fear for some populations. ... For that reason and others, WHO has begun referring to the virus as "the virus responsible for COVID-19" or "the COVID-19 virus" when communicating with the public. Neither of these designations are [sic] intended as replacements for the official name of the virus as agreed by the ICTV.
Unknown parameter|url-status=
ignored (help)
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "AntiviralCleavage" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "AtlanticSuccess" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "BBC-Named" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "BronxTiger" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CDCAbout" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CDCanimals" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CD147" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CellWalls" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CoronavirusStudyGroup" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "CurrentOrigin" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "DWPangolins" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "early" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "econ-anatomy-killer" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "ElSahly" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Eurosurveillance" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "ForbesOrigin" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "FromHere" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "gisaid" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "GuardianLeap" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "GZM-20200220" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "IJID-interm-host" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Isolation" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Kessler17Apr2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Kuo21Jan2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "LancetBinding" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "LancetCharacteristics" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "LancetClinical" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "LancetLoad" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Letko22Jan2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "LiMar2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NatGeoSoap" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "nature feb2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NaturePang" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NaturePeakLoad" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NatureTemporalShedding" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NBCSpread" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NCBI-Bat" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NCBI-Bat2" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NCBI-Bat3" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NEJM-Dynamics" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NEJM-FirstUS" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NEJM-Novel" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NEJM-Stability" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NextstrainJanuary" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NextstrainPhylogeny" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NIH-Structure" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "November case" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NYT-Ban" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "NYT6" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "oie.int" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "PopSciJan" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "pmid32014114" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Rejects" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Rocklov" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "ScienceFlawed" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "ScienceRapid" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "SCI-20200219" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "SCLSModeling" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "STAT-Severity" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "SunChinaAfrica" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "TelegraphPangolins" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "USDAtiger" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "VirologicalInitial" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "VirusesPangolins" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHOChinaJoint" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO-PHEIC" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO-SR12" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO-SR69" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO-Workplace" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WHO21Jan2020" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WongRecombination" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "Wong2019" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WSJPandemic" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "WuStructure" defined in <references>
is not used in prior text.
<ref>
tag with name "XivDecoding" defined in <references>
is not used in prior text.