Alice Brady
Alice Brady | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mary Rose Brady Oṣù Kọkànlá 2, 1892 New York City, U.S. |
Aláìsí | October 28, 1939 New York City, U.S. | (ọmọ ọdún 46)
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1914–1939 |
Olólùfẹ́ | James L. Crane (m.1919–div.1922) |
Àwọn ọmọ | 1[1] |
Parent(s) |
|
Alice Brady (Orúkọ Àbísọ rẹ ni Mary Rose Brady; Ọjọ́ ìbí je November 2, 1892 si October 28, 1939) jẹ́ Òṣèré kàn ní orílé èdè Améríkà tí ì bẹrẹ iṣé náà ni àkókò tí wọn ń pé ní Silent Era, èyí tí o padà di àsìkò tí wọn pè ní Sound Film/talkies. O sìse Títí di oṣù mẹ́fà kí ó pàdúnu èmi rẹ sórí ààrùn Jẹjẹrẹ Cancer ní ọdún 1939. Àwọn eré Fíìmù rẹ náà ní; My Man Godfrey ni 1936, nínú rẹ̀ ní ó tí ṣeré gẹgẹ bí Carole Lombardi àti nínú fíìmù "In Old Chicago ní ọdún 1937 èyí tí ì gbà àmi w Akádẹ́mì Fún Best Supporting Actress. Ni ọdún 1960, àwọn orúkọ fún àmì ẹ̀yẹ Hollywood Walk of Fame Motion pictures, èyí tí orúkọ rẹ̀ náà wà lára wọn fún àwọn ohùn tí o tí ṣe àfikún nínú iṣẹ eré ṣíṣe. Àmì ẹ̀yẹ tí o gbà wá ni 6301 Hollywood Boulevard.[2] O jẹ́ òṣèré tó gba Amì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì bí Obìnrin Òṣeré Kejì tí ó Dídárajùlọ.
Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mary Rose Brady jẹ́ ẹni tí wøn bí sí ìlú Newyork. Bàbá tí ó bi, William A. Brady jẹ́ Àgbà gbóògì kan nínú eré ìtàgè ṣíṣe. [3]Ìyá rẹ̀, Òṣèré Faranseé, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Rose Marie Rene jáde láyé ní ọdún 1896[4] Rose Brady jẹ́ ẹni tí o nífẹẹ sí eré ṣíṣe láti ìgbà èwe. Ó sí kọ́kọ́ wọ itage nígbà tí o wà ní ọmọ ọdún mérìǹlá, ó sí gbà iṣẹ àkọkọ rẹ sí Broadway theatre ni ọdún 1911 nígbà tí o wà ní ọmọ ọdún méjìdíńlógún èyí tí bàbá rẹ̀ náà kópa nínú eré náà.[5] Iṣẹ́ tí ó Yàn ni ṣíṣe== Mary Rose Brady kọ́kọ́ bẹrẹ iṣẹ ìtàgè ṣíṣe ni 1911 ní New haven nínú Eré Operetta tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "The Balkan Princess .[4] Ní ọdún 1913, Brady kópa nínú "A Thief for a night" pẹlu John Barrymorell tí P.G Wodehouse kọ àti John Stapleton kọ́ gẹgẹ bí Ìtàn Novel, àti A Gentleman Of Leisure ní ilé ìwòran Theatre ti McVicker ni ìlú Chicago.[6] O tẹsiwaju láti tún seré ṣùgbọ́n nínú àwọn eré tí bàbá rẹ̀ ṣe títí ọ fí pé ọmọ ọdún méjìlélógún. Ní ọdún 1931, óò wá nínú Àfihàn eré tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Mourning Becomes Electral láti ọwø Eugene O'Neill.[7] Ìyàwó bàbá rẹ tí í ṣe Grace George tí bàbá rẹ̀ fẹ nígbà tí Alice wá ní kékeré bí ọmọ ọkunrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ William A. Brady Jr.
Brady's father moved into movie production and presentation in 1913,[citation needed] with his World Film Company, and Brady soon followed along after him, making her first silent feature appearance in As Ye Sow in 1914. She appeared in 53 films in the next 10 years, all while continuing to perform on stage, the film industry at the time being centered in New York.[citation needed]
Ní ọdún 1923, Óò dẹkùn láti má ṣe eré Fíìmù Àgbéléwò, èyí tí o wà bosi orí kí a má ṣe eré orí Ìtàgè, èyí tí kò sí ṣe tí tí di ọdún 1933, Nígbà náà ni ó wá lọ sí Hollywood In 1923, she stopped appearing in films to concentrate on stage acting, and did not appear on the screen again until 1933, when she made the move to Hollywood leyin èyí ní ó kopa ninu "When ladies Meet ní ọdún 1933" , èyí jẹ́ eré àkọkọ tí yóò jẹ́ Sound Film ati kí a má ya fọ́tò. Àti ìgba náà ni ó tí ń ṣíṣe takuntakun Títí ó fi jáde láyé, àwọn eré tí o tí ṣe náà jẹ́ Márùndinlọ́gbọ̀n tí o ṣe ninu ọdún méje. Eré tí ó ṣe kẹ́yìn ni "Young Mr. Lincoln' ní ọdún 1939.
Ìgbé ayé àti Ìgbẹ̀yín ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Brady fẹ òṣèré tí ó ń jẹ́ James Crane Cranell lati ọdún 1919 dé 1922 èyí tí ó jẹ́ ọdún tí wọn kọ r'awọn sílẹ. Wọn jọ ṣeré ninú àwon eré wọnyi: His Bridal Night ní 1919, "Sinnners" ní 1929 àti "A dark Lantern ni 1920. Àwọn méjèèjì bí ọmọ ọkunrin kàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Donald.
Brady Kù ní ọjọ kéjìdínlógbọ̀n, oṣù kọkànlá ọdún 1939, èyí tí o jáde láyé látàri Ààrùn Jẹjẹrẹ (cancer).[8]
Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fún ìkópa rẹ gẹgẹ bí Mrs. Molly O' Leary tí o jẹ́ ẹyà Catherine Ó' Leary ní ọdún 1937 ní Chicago, O gbà àmi ẹ̀yẹ Akádẹ́mì fún Best Supporting Actress.[9] Wọn Yan láti gbà àmi ẹ̀yẹ yìí na ni ọdún kan fún ìkópa rẹ nínú eré míràn tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "My Man Godfrey.[citation needed]
Àwọn Ìtàn tí a gbọ jẹ́ kí ọ yé wá pé ni àpéjọ Presentation funÀmì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì, Ọkùnrin kan tí ó wá sí gbàgede láti bá Brady gba Àmì Ẹ̀yẹ Oscar fún Best Supporting Actress ní ọdún 1943 nítorí pé Brady ó sí níbẹ láti gba Àmì ẹyẹ náà, gbà àmi náà o sí salọ, èyí tí wọn kò rí, wón kó sí rí Ami ẹ̀yẹ náà gbà lọ́wọ́ rẹ̀. Ṣùgbọ́n Akádẹ́mì wá òmíràn láti fi dí èyí tí wọn kò mọ fún Brady .[10]
Amò gẹgẹ bí ìwàádi tí àwọn onií ìròyìn ṣe, Ẹni tí ó darí eré ti ó fí gbà àmi ẹyẹ náà, Henry King ni ó padà ba gbà àmi náà ni òjò náà, tí àwọn Ọ̀rẹ Brady padà bá gbà láti gbé lọsí ilé ní alé ọjọ́ náà. Àwọn tí wọn ja ewé Olúborí gbà àmi ẹyẹ ṣugbọn lẹyìn tí wọn gbé delé, wọn sì lọ dapadà sí Akádẹ́mì láti lè jẹ́ kí wọn kọrúkú sórí Ami ẹ̀yẹ náà. Ní ọdún 2016, Olivia Rutigliano tí ó jẹ́ aṣojú Oscar ṣe àkíyèsí pé Brady tẹ̀lẹ́ ìlànà, èyí tí ó padà jẹyọ síta pé Akádẹ́mì fún ní ìdàrò Ami ẹye: Myths|url=https://www.forbes.com/sites/peterdecherney/2016/02/24/stolen-oscars-history-markets-myths/#48013ab51ea6%7Caccess-date=9 March 2017|work=Forbes|date=24 February 2016}}</ref>
Àwọn Eré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A sample of her more than 80 films includes:
Silent
- The Boss (1915 World Film) Lost
- A Cup of Chance (1915 General Film)
- The Lure of Woman (1915 World) (Incomplete; Library of Congress)
- The Rack (1915 World) Lost
- The Ballet Girl (1916 World) Lost
- The Woman in 47 (1916 World) (Extant; BFI National Film & TV, London)
- Then I'll Come Back to You (1916 World) Lost
- Tangled Fates (1916 World) Lost
- La Bohème (1916 World) La vie de Bohème (*short) (Extant; Geo. Eastman House)
- Miss Petticoats (1916 World) (Extant; Geo. Eastman House)
- The Gilded Cage (1916 World) (*Extant; Library of Congress, Geo. Eastman, BFI, London)
- Bought and Paid For (1916 World) Lost
- A Woman Alone (1917) Lost
- A Hungry Heart (1917) Lost
- The Dancer's Peril (1917) (*Extant; DVD Grapevine video, Geo. Eastman, Cineteca Del Friuli)
- Darkest Russia (1917) (Incomplete; Library of Congress)
- Maternity (1917) Lost
- The Divorce Game (1917) Lost
- A Self-Made Widow (1917) Lost
- Betsy Ross (1917) (*extant; online, Grapevine DVD)
- A Maid of Belgium (1917)
- Her Silent Sacrifice (1917) (*extant; Library of Congress)
- Woman and Wife (1918)
- The Knife (1918)
- The Spurs of Sybil (1918)
- The Trap (1918 World)
- At the Mercy of Men (1918 Select)
- The Ordeal of Rosetta (1918 Select)
- The Whirlpool (1918 Select)
- The Death Dance (1918 Select)
- The Better Half (1918 Select)
- Her Great Chance (1918 Select)
- In the Hollow of Her Hand (1918 Select)
- The Indestructible Wife (1919 Select)
- The End of the Road (1919 Public Health Films)
- The World to Live In (1919 Select)
- Marie Ltd. (1919 Select)
- Redhead (1919 Select)
- His Bridal Night (1919 Select)
- The Fear Market (1920 Realart)
- Sinners (1920 Realart)
- A Dark Lantern (1920 Realart)
- The New York Idea (1920 Realart) (*extant; George Eastman House)
- Out of the Chorus (1921 Realart)
- The Land of Hope (1921 Realart) Lost
- Little Italy (1921 Realart) Lost
- Dawn of the East (1921 Paramount-Realart ) Lost
- Hush Money (1921 Paramount) Lost
- A Trip to Paramountown (1922) (*short)
- Missing Millions (1922 Paramount) Lost
- Anna Ascends (1922 Paramount) (*6 min. fragment)
- The Leopardess (1923 Paramount) Lost
- The Snow Bride (1923 Paramount) Lost
Sound
- When Ladies Meet (1933 MGM)
- Beauty for Sale (1933 MGM)
- Stage Mother (1933 MGM)
- Broadway to Hollywood (1933 MGM)
- The Gay Divorcee (1934 RKO)
- Miss Fane's Baby Is Stolen (1934 Paramount)
- Gold Diggers of 1935 (1935 Warner Brothers)
- Let 'Em Have It (1935 United Artists)
- Three Smart Girls (1936 Universal)
- Go West, Young Man (1936 Paramount)
- My Man Godfrey (1936 Universal)
- The Harvester (1936 Republic Pictures)
- Call It a Day (1937 Warner Brothers)
- One Hundred Men and a Girl (1937 Universal)
- In Old Chicago (1937 20th Century-Fox)
- Mr. Dodd Takes the Air (1937 Warner Brothers)
- Goodbye Broadway (1938 Universal)
- Zenobia (1939 United Artists)
- Young Mr. Lincoln (1939 20th Century-Fox)
-
La Bohème, 1916
-
Miss Petticoats, 1916
-
Bought and Paid For, 1916
-
The Gilded Cage, 1916
-
The Hungry Heart, 1917
-
The Dancer's Peril, 1917
-
A Self-Made Widow, 1917
-
Her Silent Sacrifice, 1917
-
Woman and Wife, 1918
-
Woman and Wife, 1918
-
The Whirlpool, 1919
-
The World To Live In, 1919
Fún kíkà itẹsiwaju
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Chicago Tribune - Historical Newspapers". Chicago Tribune.
- ↑ "Walk of Fame Stars-Alice Brady". Hollywood Chamber of Commerce/Walk of Fame.
- ↑ "William A. Brady". IBDB.com. Internet Broadway Database.
- ↑ 4.0 4.1 Halasz, George (February 24, 1929). "Actress Without Temperament". The Brooklyn Daily Eagle: p. 80. https://www.newspapers.com/clip/57466548/alice-brady/.
- ↑ "The Balkan Princess". IBDB.com. Internet Broadway Database.
- ↑ McIlvaine 1990, p. 301
- ↑ "Alice Brady". IBDB.com. Internet Broadway Database.
- ↑ Hischak, Thomas S. (June 16, 2017). 1939: Hollywood's Greatest Year. Rowman & Littlefield. ISBN 9781442278059. https://books.google.com/books?id=u4Q1DgAAQBAJ&q=alice+brady+cancer+october+1939&pg=PA280.
- ↑ Quinlan, David (1996) Quinlan's Film Stars, 4th edn., B.T. Batsford, ISBN 0-7134-7751-2, p. 63
- ↑ "Heritage Auction Galleries "Signature Music & Entertainment Memorabilia Auction″ Catalog Available Online (October 2008)". Movie Prop Collecting with Jason DeBord's Original Prop Blog Film & TV Prop, Costume, Hollywood Memorablia Pop Culture Resource. September 6, 2008.
External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Literature on Alice Brady
- Alice Brady portrait 1910s
- Alice Brady at the NY Public Library Billy Rose Collection
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Alice Brady |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- Pages with script errors
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- All articles with unsourced statements
- Articles with unsourced statements from October 2021
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with unsourced statements from May 2022
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1892
- Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1939
- American film actresses
- American silent film actresses
- American stage actresses
- Best Supporting Actress Academy Award winners
- Deaths from cancer in New York (state)
- 20th-century American actresses
- Actresses from New York City
- Articles containing video clips
- Broadway theatre people
- Àwọn ẹlẹ́bùn Akádẹ́mì Obìnrin Òṣeré Dídárajùlọ 2k