Cloris Leachman
Cloris Leachman ni a bini óṣu April, ọdun 1926 to si ku ni Óṣu january, ọdun 2021. Cloris jẹ óṣèrè lóbinrin ati alawada to si ṣiṣẹ fun ọgọrin ọdun[1].
Igbèsi Àyè Arabinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Leachman ni a bi fun Cloris ati Berkeley Claiborne si ilu Des Moines, Iowa[2].
Cloris gba ẹkọ ọfẹ lati kẹẹkọ ni Studio óṣèrè lọkunrin ni New York City labẹ akoso Elia Kazan[3].
Lati ọdun 1953 si ọdun 1979, Leachman fẹ̀ George Englund ti wọm si ọmọkunrin mẹrin ati ọmọ óbinrin kan;Bryan (Ọmọ naa ku ni ọdun 1986), Morgan, Adam, Dinah ati George[4][5] .leachman jẹ eni ti kó Kin sin ọlọhun rara[6][7].
Ni óṣu January, ọdun 2021, óṣèrè lóbinrin naa ku si oju órun ni ilè rẹ Encinitas, California lóri aisan stroke ati Covid-19 ti wọn sin ni óṣu february, ọdun 2021[8][9].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Cloris lọsi ilè iwè Theodore Roosevelt. Lẹyin ti óṣèrè lóbinrin naa jade ni ilè iwè ti High ló lọsi ilè iwè giga ti Northwestern[10].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Cloris gba Award ti Primetime Emmy, Ere ti Academy ilẹ British, Golden Globe, Daytime Emmy ati Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[11][12][13].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.britannica.com/biography/Cloris-Leachman
- ↑ http://www.filmreference.com/film/76/Cloris-Leachman.html
- ↑ https://www.empireonline.com/movies/news/award-winning-actor-cloris-leachman-dies-aged-94/
- ↑ https://www.cheatsheet.com/entertainment/cloris-leachman-was-once-in-a-love-triangle-with-her-husband-and-another-hollywood-legend.html/
- ↑ https://news.amomama.com/292920-cloris-leachman-was-madly-love-her-once.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20120302232507/http://www.grandparents.com/gp/content/expert-advice/celebrity/article/cloris-leachman-loves-her-grandkids.html
- ↑ https://www.huffpost.com/entry/cloris-leachman-raising-hope_b_1606927
- ↑ https://www.nytimes.com/2021/01/27/arts/television/cloris-leachman-dead.html
- ↑ https://www.etonline.com/cloris-leachmans-cause-of-death-was-stroke-covid-19-contributed-160814
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-01-27. Retrieved 2022-11-21.
- ↑ https://www.businessinsider.com/actors-who-won-the-most-emmys-of-all-time-2017-9?r=US&IR=T
- ↑ https://m.imdb.com/name/nm0001458/awards
- ↑ https://www.emmys.com/bios/cloris-leachman