Dianne Wiest
Dianne Wiest | |
---|---|
Wiest in 2009 | |
Ọjọ́ìbí | Dianne Evelyn Wiest 28 Oṣù Kẹta 1948 Kansas City, Missouri, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Maryland |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1970–present |
Àwọn ọmọ | 2 |
Dianne Evelyn Wiest[1] ( /wiːst/;[2] tí a bí ní oṣù kẹta ọjọ́ kejì-dín-lọ́gbọ̀n, ọdún 1848)[3][4][5][6] jẹ́ òṣèré Ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó ti gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀rí méjì fún òṣèré àtìlẹ́yìn tí ó dára jùlọ fún ọdún 1986 nínú Hannah and Her sisters àti ọdún 1994 Bullets over Broadway (méjèjì èyí tí Woody Allen ṣe ìtọsọ́nà fún), ìkan lára rẹ̀ ni Golden Globe Award fún Bullets over Broadway, ti ọdún 1997 Primetime Emmy Award fún òṣèré àlejò tó táyọ̀ jù nínú jara dírámà kan fún Road to Avonlea, àti ti ọdún 2008 Primetime Emmy Award fún òṣèré obìnrin tó dára jùlọ pẹ̀lú ìyàtọ̀ nínú jara dírámà fún In Treatment. Ní àfikún wọ́n Yàn án fún à ti gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀rí èyí tí ó jẹ́ "Academy Award fún ọdún 1989 Parenthood.
Àwọn Ìfihàn fíìmù láti ọwọ́ Wiest ní wọ̀nyí: Footloose (ní ọdún 1984); Woody Allen's The Purple Rose of Cairo (ọdún 1985), Radio Days (ọdún 1985), àti September (1987); The Lost Boys (ọdún 1987), Bright Lights, Big City (ọdún 1988), Edward Scissorhands (ọdún 1990), Little Man Tate (ọdún 1991) The Birdcage (ọdún 1996) Practical Magic (ọdún 1998), Dan in Real Life (2007), Synecdoche, New York (ọdún 2008), Rabbit Hole (2010), Sister's (ọdún 2015), Let Them All Talk (ọdún 2020) àti I Care a Lot (ọdún 2020). Ó tún farahàn nínú jara tẹlifísàn "Law and Order" (ọdún 2000 sí ọdún 2002), àti ti àpanilẹ́rìn-ín CBS "Life in Pieces" (ọdún 2015 sí ọdún 2019).
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Wiest ní Kansas City, Missouri. Ìyá rẹ̀, Anne Stewart (née Keddie), jẹ́ nọ́ọ̀sì. Bàbá rẹ̀, Bernard John Wiest, jẹ́ adárí kọ́lẹ́ẹ̀jì kan àti òṣìṣẹ́ ìlera ìtọjú ọpọlọ fún U.S. Army. Ìyá rẹ̀ jẹ́ Scottish, láti Auchtermuchty, nígbà tí bàbá rẹ̀ jẹ́ American ti Croatia àti ìran ara German.int.[7] Wọ́n pàdé ara wọn ní Algiers.[8][9][10] Wiest ní ọmọkùnrin méjì tó pẹ̀lú ẹ̀ láti ọwọ́ òbí rẹ̀, Greg àti Don. Ìpinnu rẹ̀ ni láti jẹ́ oníjó ballet, ṣùgbọ́n ó yípadà ibi-àfẹdé rẹ̀ sí ìtàgé ní àwọn ọdún àgbà rẹ̀ ní Ilé-ìwé gíga Nurnberg American High School. [11] Wiest parí ilé-ẹ̀kọ́ gíga láti University of Maryland ní ọdún 1969 pẹ̀lú àléfà kan ní Iṣẹ́-ọnà àti sáyẹnsì.[12]
Ìgbésí Ayé Ti Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wiest wà ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àṣọjà tálẹ́ńtì rẹ̀ Sam Cohn fún ọdún mẹ́ta ní àárín ọdún 1980.[13][14] Ó' gba àwọn ọmọbìnrin méjì sọ́dọ̀: Emily àti Lily.
Àwọn Iṣẹ́ Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1980 | It's My Turn | Gail | as Diane Wiest |
1982 | I'm Dancing as Fast as I Can | Julie Addison | |
1983 | Face of Rage | Rebecca Hammil | |
1983 | Independence Day | Nancy Morgan | |
1984 | Falling in Love | Isabelle | |
1984 | Footloose | Vi Moore | |
1985 | The Purple Rose of Cairo | Emma | |
1986 | Hannah and Her Sisters | Holly | |
1987 | Radio Days | Bea | |
1987 | September | Stephanie | |
1987 | The Lost Boys | Lucy Emerson | |
1988 | Bright Lights, Big City | Mrs. Conway | |
1989 | Parenthood | Helen Buckman | |
1989 | Cookie | Lenore Voltecki | |
1990 | Edward Scissorhands | Peg Boggs | |
1991 | Little Man Tate | Jane Grierson | |
1994 | Bullets over Broadway | Helen Sinclair | |
1994 | Cops & Robbersons | Helen Robberson | |
1994 | The Scout | Doctor H. Aaron | |
1995 | Drunks | Rachel | |
1996 | The Associate | Sally Dugan | |
1996 | The Birdcage | Louise Keeley | |
1998 | Practical Magic | Aunt Bridget 'Jet' Owens | |
1998 | The Horse Whisperer | Diane Booker | |
2001 | I Am Sam | Annie Cassell | |
2002 | Merci Docteur Rey | Elisabeth Beaumont | |
2005 | Robots | Lydia Copperbottom | Voice only |
2006 | A Guide to Recognizing Your Saints | Flori Montiel | |
2007 | Dedication | Carol | |
2007 | Dan in Real Life | Nana Burns | |
2008 | Passengers | Toni | |
2008 | Synecdoche, New York | Ellen Bascomb/Millicent Weems | |
2009 | Rage | Miss Roth | |
2010 | Rabbit Hole | Nat | |
2011 | The Big Year | Brenda Harris | |
2012 | Darling Companion | Penny Alexander | |
2012 | The Odd Life of Timothy Green | Ms. Crudstaff | |
2014 | The Humbling | Carol Stapleford | |
2015 | Five Nights in Maine | Lucinda | |
2015 | Sisters | Deana Ellis | |
2018 | The Mule | Mary Stone | |
2020 | I Care a Lot | Jennifer Peterson | |
2020 | Let Them All Talk | Susan | |
2022 | My Father's Dragon | Voice only; post-production |
Tẹlifísàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1975 | Zalmen: or, The Madness of God | Nina | Television film |
1978 | Great Performances: Out of Our Father's House | Elizabeth Gertrude Stern | Television film |
1997 | Road to Avonlea | Lillian Hepworth | 1 episode |
1999 | The Simple Life of Noah Dearborn | Sarah McClellan | Television film |
2000 | The 10th Kingdom | The Evil Queen/Christine White | Miniseries, 10 episodes |
2000–02 | Law & Order | D.A. Nora Lewin | Lead role, 46 episodes |
2001 | Law & Order: Criminal Intent | D.A. Nora Lewin | 1 episode |
2001–02 | Law & Order: Special Victims Unit | D.A. Nora Lewin | 2 episodes |
2004 | The Blackwater Lightship | Lily Devereux Breen | Television film |
2004 | Category 6: Day of Destruction | Secretary of Energy Shirley Abbott | 2 episodes |
2008–09 | In Treatment | Dr. Gina Toll | Main role, 17 episodes |
2008 | The Return of Jezebel James | Talia Tompkins | 2 episodes |
2011 | Woody Allen: A Documentary | Herself | 2 episodes |
2014 | The Blacklist | Ruth Kipling | 1 episode |
2015–19 | Life in Pieces | Joan Short | Main role, 79 episodes |
2021–present | Mayor of Kingstown | Miriam McClusky | Main role, ongoing series |
Orí Ìtàgé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Deaths: Wiest, Dr. Bernard". The Advocate (Louisiana) (NewsBank). 3 May 1986. http://nl.newsbank.com/nl-search/we/Archives?p_text_direct-0=0EB473DB10C4FF31&p_field_direct-0=document_id.
- ↑ Àdàkọ:YouTube, presenters' announcing her win at the 1987 awards confirm pronunciation, accessed August 20, 2014
- ↑ "DIANNE WIEST TRYING TO AVOID YET ANOTHER ROLE TRAP". Chicago Tribune. December 28, 1990. Retrieved March 3, 2021.
- ↑ "Oscar Winner Dianne Wiest: I'm Struggling to Pay My Rent". The Hollywood Reporter. January 25, 2015. Retrieved March 3, 2021.
- ↑ "Dianne Wiest". Rotten Tomatoes. Retrieved March 3, 2021.
- ↑ "Dianne Wiest - Turner Classic Movies".
- ↑ Dianne Wiest biography. Film Reference.com.
- ↑ Bennetts, Leslie (March 18, 1987). "Dianne Wiest Makes Neurosis A Success Story". The New York Times. https://www.nytimes.com/1987/03/18/garden/dianne-wiest-makes-neurosis-a-success-story.html.
- ↑ "NewsLibrary Search Results". nl.newsbank.com.
- ↑ "NewsLibrary Search Results". nl.newsbank.com.
- ↑ "Dianne Wiest Lauded in German Press for Role in Senior Play 'Pygmalion,' NHS Trichter, Vol 15, No 3, fall 2003, p. 19.
- ↑ The Women of Maryland: Alumni Who Have Made A Difference Archived 2013-01-19 at the Wayback Machine.. University of Maryland Women Alumni.
- ↑ Weber, Bruce (May 6, 2009). "Sam Cohn, Powerful Talent Broker, Dies at 79". The New York Times. https://www.nytimes.com/2009/05/07/arts/07cohn.html.
- ↑ "Dianne Wiest -- Hannah's Fragile Sister". Orlando Sentinel. April 6, 1987.
- ↑ "Happy Birthday, Wanda June – Broadway Play – Original | IBDB". www.ibdb.com. Retrieved 2021-04-04.
- ↑ "Solitaire / Double Solitaire – Broadway Play – Original | IBDB". www.ibdb.com. Retrieved 2021-04-04.
- ↑ "Ivanov". Williamstown Theatre Festival (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-04.
- ↑ Rich, Frank (1984-02-03). "STAGE: 'SERENADING,' BY LANFORD WILSON" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/1984/02/03/theater/stage-serenading-by-lanford-wilson.html.
- ↑ "'Hunting Cockroaches' Starring Ron Silver and Dianne Wiest Opens Off-Broadway". AP NEWS. Retrieved 2021-04-04.
- ↑ "Les Liaisons Dangereuses". Williamstown Theatre Festival (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-04.
- ↑ "In the Summer House – Broadway Play – 1993 Revival | IBDB". www.ibdb.com. Retrieved 2021-04-04.
- ↑ "Memory House". Playwrights Horizons (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2015-04-21. Retrieved 2021-04-04.
- ↑ BWW News Desk. "Classic Stage Company Presents Dianne Wiest in THE FOREST". BroadwayWorld.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-04.
- ↑ Isherwood, Charles (2015-02-12). "Review: 'Rasheeda Speaking' Finds a Chilling Place to Work" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2015/02/12/theater/review-rasheeda-speaking-finds-a-chilling-place-to-work.html.