Gale Sondergaard
Gale Sondergaard | |
---|---|
Sondergaard in 1940 | |
Ọjọ́ìbí | Edith Holm Sondergaard Oṣù Kejì 15, 1899 Litchfield, Minnesota, U.S. |
Aláìsí | August 14, 1985 Woodland Hills, Los Angeles | (ọmọ ọdún 86)
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1936–1983 |
Olólùfẹ́ | Neill O'Malley (m. 1922; div. 1930) Herbert J. Biberman (m. 1930; died 1971) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Gale Sondergaard je óṣèrè lóbinrin ilẹ america ti a bini óṣu febuary, ọdun 1899 to si ku ni óṣu August, ọdun 1985[1].
Igbesi Ayè Arabinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ósèrè lóbinrin naa ni a bisi Ilu Litchfield, Minnesota fun Hans Sondergaard ati Anna Kirstine Søndergaard[2].
Sondergaard fẹ́ òṣèré lọ́kùnrin Neill O'Malley ní ọdún 1922 tí wọ́n sì pínyà ní ọdún 1930. Ní oṣù May ní ọdún 1930, Òṣèré binrin náà fẹ́ Herbert Biberman ní ìlú Philadelphia, Pennsylvania. Ọkọ náà kú ní ọdún 1971. Tọkọ Taya náà gba àwọn ọmọ méjì tọ́ (Joan Kristine Biberman àti Daniel Hans Biberman)[3][4].
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìsàn rọpá rọsè, Sondergaard kú sí Ilé ìwòsàn tí Motion Picture àti television ní ìlú Woodland Hills, California ní ọdún 1985 lóri àìsàn tí àwọn òyìnbó pè ní Vascular thrombosis[5].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Baba Gale ṣiṣẹ ni ilè iwè giga ti Minnesota nibi ti óṣèrè lóbinrin naa ti jẹ akẹẹkọ ti imọ èrè itage[6].
Àmì Ẹ̀yẹ àti Ìdánilọ́lá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Òṣèré lóbinrin nàá gba Ebun Akademi bí Obìnrin Òṣèré tó ranilọ́wọ́ Keji Didarajulo[7][8].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://broadcast41.uoregon.edu/biography/sondergaard-gale
- ↑ https://books.google.com.ng/books?id=IbpwDl1nt0MC&pg=PA196&redir_esc=y#v=onepage&q&f=false
- ↑ https://catalogue.swanngalleries.com/Lots/LotDetails?salename=%28FILM.%29-Archive-of-blacklisted-actress-Gale-Sondergaard-and--2473%2B%2B%2B%2B%2B%2B92%2B-%2B%2B740754&saleno=2473&lotNo=92&refNo=740754
- ↑ https://m.whosdatedwho.com/dating/gale-sondergaard
- ↑ https://www.latimes.com/archives/la-xpm-1985-08-15-mn-1616-story.html
- ↑ https://www.nytimes.com/1985/08/16/business/gale-sondergaard-actress-played-villainesses-in-films.html
- ↑ http://awardsandwinners.com/winner/?name=gale-sondergaard&mid=/m/02rwj9
- ↑ https://m.timesofindia.com/topic/Gale-Sondergaard/awards