Jump to content

Tilda Swinton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tilda Swinton
Swinton at the 2018 Vienna International Film Festival
Ọjọ́ìbíKatherine Matilda Swinton
5 Oṣù Kọkànlá 1960 (1960-11-05) (ọmọ ọdún 64)
London, England
Ẹ̀kọ́Murray Edwards College, Cambridge
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1984–present
WorksTilda Swinton filmography
Alábàálòpọ̀
  • John Byrne (playwright)
  • John Byrne (1989–2003)
  • Sandro Kopp (2004–present)
Àwọn ọmọ2, including Honor Swinton Byrne
Parent(s)
  • John Swinton of Kimmerghame (father)
ẸbíClan Swinton
AwardsList of awards and nominations received by Tilda Swinton

Tilda Swinton je óṣèrè lobinrin ti ilẹ British osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Igbesi Ayè Arabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Katherine Matilda Swinton ni a bi ni ọjọ kàrun óṣu November ọdun 1960 si ilu london fun Judith Balfour (1929-2012) ati Sir John Swinton (1925-2018). Baba óṣère lobinrin naa jẹ óṣisẹ fẹyinti major-general ti ólógun ilẹ ati ọga lieutenant ti Berwickshire (1989-2000), Iya rẹ si jẹ ọmọ ilẹ Australia[2][3].

Ni ọdun 1997, Tilda bi ibeji Honor ati Xavier Swinton Byrne fun John Byrne ti o si gbe scotland fun ogun ọdun[4]. Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ èrè oritage lati igba ti o ti wa ni ilè iwe. Swinton ló ọdun meji gẹgẹbi ẹni jọwọ ara rẹ silẹ lati ṣè iranlọwọ ofẹ ni ilẹ South Africa ati Kenya ki o to lọ si ile iwe giga ti Cambridge.

Swinton lọsi Ilè ẹkọ Queen's Gate, Ilè ẹkọ Awọn ọdọmọbinrin ètó ilèra west ati Fettes College fun igba diẹ. Ni ọdun 1983, Swinton kawe yege ni Ilè iwè giga ti Cambridge lori imọ social ati science ti óṣẹlu[5].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tilda gba ami ẹyẹ Akademi, ami ẹyẹ BAFTA ati ami ẹyẹ Independent spirit. Ni ọdun 2020, New York Times ka óṣere lobinrin naa kun gẹgẹbi ọkan lara awọn óṣere to pegede julọ ni 21st century[6][7].

Swinton gba Cup ti Volpi gẹgẹbi óṣèrè lobinrin to darajulọ ninu ere Edward II nibi ti ó ti ṣèrè gẹgẹbi Isabella ti ilẹ france. Óṣèrè lobinrin naa gba award ti Richard Harris lati ọdọ ere agbelewo independent award ti ilẹ British fun ipa rẹ ninu ere igbelewo industry ti ilẹ British[8]. Ni ọdun 2020, Swinton gba ami idanilọla ti fellowship Institute ere igbelewo ti ilẹ́ British fun ipa ribi ribi ti oun ko lati gbè àṣa filmu larugẹ ati itọrẹ́ anu[9].