Tunde Kelani
Tunde Kelani | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Tunde Kelani 26 Oṣù Kejì 1948 Lagos, British Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | London Film School |
Iṣẹ́ | Filmmaker |
Website | mainframemovies.tv |
Túndé Kèlání ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejì, ọdún 1948 (born 26 February 1948),jẹ́ gbajú gbajà olùgbéré jáde,ayàwòrán, adarí eré àti Onímọ̀ nípa Sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ni TK.[1] Ohun tí TK mọ̀ọ́ṣe ju ni kí ó gbe eré tí ó polongo àṣà àti ìṣe Yorùbá tí ó nítàn tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú, àkọsílẹ̀, ẹ̀kọ́, àti ìmóríwú, tí ó si tún ń dà ní lára ya nínú àṣà Yorùbá jáde nílẹ̀ Nàìjíríà Yorùbá.[2]
Ìgbé ẹwà Yorùbá rẹ̀ ga
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tk tún ma ń gbìyànjú nínú ọ̀pọ̀ eré orí ìtàgé tí ó ba gbé jáde láti ṣàmúlò àṣàyàn èdè Yorùbá yó dángájíá láàrín ìtàn eré aládùn rẹ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Bí àpẹrẹ, nínú sinimá : Kò ṣé Gbé, Ólekú, Thunder Bolt (Ẹdun Àrá), The Narrow Path, White Handkerchief, Màámi àtiDazzling Mirage.[3][4]
Ìbẹ̀rẹ̀ aye rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbà èwe rẹ̀, wọ́n mu lọ sí Abẹ́òkúta, láti máa gbé pẹ̀lú àwọn òbí òbí rẹ̀. Àwọn ọgbọ́n , ìmọ̀ Òun òye tí ó rí kójọ láti ọ̀dọ̀ àwọn òbí óbí rẹ̀ tí wọ́n kún fọ́fọ́ nibi àṣà Òun ìṣe Yorùbá yí àti ìrírí rẹ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ tí ó ní London Film School nibi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ni ó fun ní ànfàní láti wà ń ipò tí ó wà lónìí. [5][6][7][8]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Tunde Kelani Biography". IMDb.
- ↑ "Help, Our culture, language dying – Tunde Kelani". Tayo Salami. Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 11 March 2011.
- ↑ "Interview with Tunde Kelani". MasterClass on Nollywood, British Film Institute. Archived from the original on 11 September 2014. Retrieved 12 December 2019.
- ↑ "Tunde Kelani". Africa Movie Academy Awards. Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 12 December 2019.
- ↑ "Juries Announced for Dubai International Film Festival's Prestigious Muhr Competition". Dubai International Film Festival. Retrieved 5 December 2012.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Tunde Kelani, Cinematographer per excellence". Saturday Newswatch.
- ↑ "Zooming in on Kelani's World". This Day Live. Archived from the original on 19 March 2012. https://web.archive.org/web/20120319190059/http://www.thisdaylive.com/articles/zooming-in-on-kelani-s-world/111637. Retrieved 17 March 2012.
- ↑ "Tunde Kelani Exclusive – I relax by working". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2012/04/tunde-kelani-exclusive-i-relax-by-working/.