Ìpínlẹ̀ Nasarawa
Ìpínlẹ̀ Násáráwá Nasarawa State | |
---|---|
Nickname(s): | |
Location of Nasarawa State in Nigeria | |
Country | Nigeria |
Date created | 1 October 1996 |
Capital | Lafia |
Government | |
• Governor[1] | Umar Tanko al-Makura (APC) |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 27,117 km2 (10,470 sq mi) |
Population (2005) | |
• Total | 2,040,097 |
• Density | 75/km2 (190/sq mi) |
GDP (PPP) | |
• Year | 2007 |
• Total | $3.02 billion[2] |
• Per capita | $1,588[2] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-NA |
Website | nasarawastate.org |
Ìpínlẹ̀ Násáráwá je ikan ninu àwon Ipinle 36 ni orile-ede Naijiria. Oluilu re ni Lafia.
Ítàn Ìdásílẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ dídásílẹ̀ ní Ọjó kínní, osù kẹwàá, Ọdún 1996 nígbà ìsèjọba Abacha, tí wọ́n pín kúrò ní ìpínlẹ̀ Plateau odè oní.[3]
Ijọba Ìbílẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ mẹ́tàlá. (Afìhàn pẹ̀lú ònkà 2006 population[4]):
Nasarawa West Senatorial District | 716,802 |
---|---|
Karu | 205,477 |
Keffi | 92,664 |
Kokona | 109,749 |
Nasarawa | 189,835 |
Toto | 119,077 |
Nasarawa North Senatorial District | 335,453 |
Akwanga | 113,430 |
Eggon | 149,129 |
Wamba | 72,894 |
Nasarawa South Senatorial District | 811,020 |
Awe | 112,574 |
Doma | 139,607 |
Keana | 79,253 |
Lafia | 330,712 |
Obi | 148,874 |
Awọn èdè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Nasarawa jẹ́ mókàndínlógbọ̀n.
Awọn èdè na wa nínú tábìlì yi ní nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Nasarawa:[5]
LGA | Languages |
---|---|
Akwanga | Mada;Duhwa; Eggon; Fulani; Gwandara; Hausa; Mama; Ninzo; Numana; Nungu |
Awe | Hausa; Fulani; Gwandara; Eggon; Goemai; Lijili; Tiv; Wapan |
Doma | Alago; Tiv; Agatu; Fulani; Hausa; |
keffi | Hausa; Fulani; :madaGadeEggon;Gbagyi; Gwandara; Koro Wachi |
Karu | Gbagyi; Gwandara; Gade |
Keana | Alago; Gwandara Tiv; Fulani |
Kokona | Gwandara;mada Fulani; Hausa; Eggon |
Lafia | Bare-Bari; Hausa; Fulani; Ake;mada: Alago; Agatu; Eggon; Goemai; Gwandara; Kofyar; Lijili; Tiv; Wapan |
Nasarawa | Hausa; Fulani; Agatu; Alago; Basa; Egbura; Eloyi; Gade; Gbagyi; Gwandara; Eggon; Tiv |
Nasarawa-Eggon | Eggon; Mada; Nungu; Fulani; Hausa |
Obi | Alago; Hausa; Fulani; Eggon; Tiv |
Toto | Egbura Agatu; Eggon; Gade; Fulani; Hausa |
Wamba | Alumu-Tesu;ninzo:mada;rindre Bu; Eggon; Hasha; Fulani; Kantana; Nungu; Toro |
Ní ìpínlè Nasarawa, orísìrísí ẹ̀yà marundinlogbon ló wà. Àwọn tí wọn ma n sọ jù nì Miligi (Koro), Alago, Mada, Gwandara, Kunari, Hausa Fulani, Gwari, Rindre, Afo, Eggon and Ebina[6]
Ilé ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpínlẹ̀ Nasarawa ni awọn Ilé ẹ̀kọ́ bí:
- College of Education, Akwanga
- Federal Polytechnic Nasarawa
- College of Agriculture in Lafia
- Isa Mustapha Agwai I Polytechnic Lafia
- Nasarawa State University
- Mewar International University ní Masaka
- Bingham University at Karu
- Hill College of Education Gwanje Akwanga
- NACAP polytechnic Akwanga
- Command secondary school Lafia
- Command secondary school Rinze
- Vocational And Relevant technology board
Ìpínlè Nasarawa ní awọn ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama bí the Federal Government Girls College, Kea.
Awon èèyàn jànkànjànkàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Imaan Sulaiman-Ibrahim – Director-General of NAPTIP
- HRH Alhaji Abdullahi Amegwa Agbo - Osana of Keana
- HRH Alhaji Ahmadu Aliyu Ogah - Andoma of Doma
- Sen. Abdullahi Adamu - National Chairman, APC
- Suleiman Odapu-Public Relations Practitioner
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ See List of Governors of Nasarawa State for a list of prior governors
- ↑ 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20.
- ↑ "This is how the 36 states were created". Pulse.ng. 24 October 2017. Retrieved 22 December 2021.
- ↑ 2006 Population Census, Federal Republic of Nigeria, National Bureau of Statistics. Archived from the original Archived 2007-07-04 at the Wayback Machine. on 2009-03-25.
- ↑ "Nigeria". Ethnologue. https://www.ethnologue.com/country/NG.